Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 23:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú ère òrìṣà láti ilé Olúwa sí pẹ̀tẹ́lẹ̀ Kídírónì ní ìta Jérúsálẹ́mù, ó sì ṣun wọ́n níbẹ̀. Ó lọ̀ ọ́ bí atíkè ó sì fọ́n ekuru náà sórí iṣà òkú àwọn ènìyàn tí ó wọ́pọ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:6 ni o tọ