Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 23:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì pàṣẹ fún Hílíkíáyà olórí àlùfáà àti àwọn, àlùfáà tí ó tẹ̀lée ní ipò àti àwọn olùsọ́nà láti yọ kúrò nínú ilé Olúwa gbogbo ohun èlò tí a ṣe fún Báálì àti Áṣérà àti gbogbo ẹgbẹ́ ogun ọ̀run. Ó sì sun wọ́n ní ìta Jérúsálẹ́mù ní pápá pẹ̀tẹ́lẹ̀ Kídírónì. Ó sì kó eérú wọn jọ sí Bétélì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:4 ni o tọ