Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 23:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Olúwa wí pé, “Èmi yóò mú Júdà kúrò pẹ̀lú níwájú mi, bí mo ti mú Ísírẹ́lì, èmi yóò sì kó Jérúsálẹ́mù, ìlú ńlá tí mo yàn àti ilé Olúwa yìí, nípa èyí tí mo sọ, ‘Níbẹ̀ ni orúkọ mi yóò wà?’ ”

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:27 ni o tọ