Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 23:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sì sí ọba kankan níwájú tàbí lẹ́yìn Jóṣíáyà tí ó dàbí rẹ̀, tí ó yí padà sí olúwa tinútinú àti gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe tọkàntọkàn pẹ̀lú gbogbo ẹ̀mí i rẹ̀, pẹ̀lú gbogbo agbára rẹ̀ ní ìbámu pẹ̀lú gbogbo òfin Móṣè.

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:25 ni o tọ