Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 23:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jòṣíáyà dúńbú gbogbo àwọn àlùfáà ibi gíga lórí pẹpẹ. Ó sì ṣun egungun ènìyàn lórí wọn. Nígbà náà, ó padà lọ sí Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:20 ni o tọ