Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 23:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gòkè lọ sí ilé Olúwa pẹ̀lú àwọn ọkùnrin Júdà, àwọn ènìyàn Jérúsálẹ́mù, àwọn àlùfáà àti àwọn wòlíì—gbogbo àwọn ènìyàn láti ibi kéékèèkéé sí ńlá. Ó kàá sí etí igbọ́ ọ wọn, gbogbo ọ̀rọ̀ tí ó wà nínú ìwé májẹ̀mú, tí a ti rí nínú ilé Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:2 ni o tọ