Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 23:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì béèrè, pé “Kí ni ọwọ́n iṣà òkú yẹn tí mo rí?”Àwọn ọkùnrin ìlú ńlá wí pé, “Ó sàmì sí iṣà òkú ènìyàn Ọlọ́run tí ó wá láti Júdà, tí ó sì kéde ìdojúkọ pẹpẹ Bétélì, ohun kan wọ̀nyí tí ìwọ ti ṣe sí wọn.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:17 ni o tọ