Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 22:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gòkè lọ sí ọ̀dọ̀ Hílíkíyà olórí àlùfáà, kí o sì jẹ́ kí ó sírò iye owó tí a mú wá sí ilé Olúwa, tí àwọn olùṣọ́nà ti gbà lọ́wọ́ àwọn ènìyàn.

Ka pipe ipin 2 Ọba 22

Wo 2 Ọba 22:4 ni o tọ