Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 22:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí wọ́n ti kọ̀ mí sílẹ̀, wọ́n sì tún ṣun tùràrí fún ọlọ́run mìíràn. Wọ́n sì mú mi bínú nípa gbogbo àwọn òrìṣà tí wọ́n ti fi ọwọ́ wọn dá. Ìbínú mi yóò ru sí ibí yìí, kì yóò sì rọlẹ̀’

Ka pipe ipin 2 Ọba 22

Wo 2 Ọba 22:17 ni o tọ