Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 21:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì, wí: Èmi le è lọ mú irú ibi báyìí wá sórí Jérúsálẹ́mù àti Júdà kí gbogbo etí olúkúlùkù tí ó gbọ́ nípa rẹ̀ le è hó.

Ka pipe ipin 2 Ọba 21

Wo 2 Ọba 21:12 ni o tọ