Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 21:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mánásè ọba Júdà ti ṣe ẹ̀ṣẹ̀ ohun ìríra. Ó ti ṣe ohun búburú jùlọ ju àwọn ará Ámórì lọ ẹni tí ó ti wà ṣáájú rẹ̀ tí ó sì ti ṣáájú Júdà sínú ẹ̀ṣẹ̀ pẹ̀lú àwọn ère rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 21

Wo 2 Ọba 21:11 ni o tọ