Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 20:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àìṣáyà dáhùn pé, “Èyí ni àmìn tí Olúwa fún ọ wí pé Olúwa yóò ṣe ohun tí ó ti ṣe ìlérí: kí òjìji lọ ṣíwájú ìgbésẹ̀ mẹ́wàá, tàbí kí ó padà lọ ní ìgbésẹ̀ mẹ́wàá?”

Ka pipe ipin 2 Ọba 20

Wo 2 Ọba 20:9 ni o tọ