Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 20:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ó jẹ́ ohun ìrọ̀rùn fún òjìji láti lọ ṣíwájú ìgbésẹ̀ mẹ́wàá,” Heṣekáyà wí pé, “Bẹ́ẹ̀ kọ́, jẹ́ kí ó lọ padà ní ìgbésẹ̀ mẹ́wàá.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 20

Wo 2 Ọba 20:10 ni o tọ