Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 20:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ padà kí o sì sọ fún Heṣekáyà, olórí àwọn ènìyàn mi pé, ‘Èyí ni ohun tí Olúwa, Ọlọ́run baba rẹ Dáfídì sọ: Mo ti gbọ́ àdúrà rẹ mo sì ti rí omijé rẹ: Èmi yóò wò ó sàn. Ní ọjọ́ kẹta láti ìsinsìnyìí, ìwọ yóò lọ sókè ilé tí a kọ́ fún Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Ọba 20

Wo 2 Ọba 20:5 ni o tọ