Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà Èlíjà sì wí fún un pé, “Dúró níbí, Èlíṣà: Olúwa ti rán mi lọ sí Jẹ́ríkò.”Ó sì dá a lóhùn pé, “Bí ó ti dájú pé Olúwa yè àti tí ìwọ náà yè, Èmi kò ní fi ọ́ sílẹ̀.” Wọ́n sì jọ lọ sí Jẹ́ríkò.

Ka pipe ipin 2 Ọba 2

Wo 2 Ọba 2:4 ni o tọ