Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 2:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ibẹ̀ Èlíṣà lọ sókè ní Bétélì gẹ́gẹ́ bí ó ti ń rìn lọ lójú ọ̀nà, àwọn ọ̀dọ́ kan jáde wá láti ìlú náà wọ́n sì fi ṣe ẹlẹ́yà. “Má a lọ sókè ìwọ apárí!” Wọ́n wí pé. “Má a lọ sókè ìwọ apárí!”

Ka pipe ipin 2 Ọba 2

Wo 2 Ọba 2:23 ni o tọ