Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 2:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wò ó,” wọ́n wí pé, “Àwa ìránṣẹ́ ni àádọ́ta ọkùnrin alágbára. Jẹ́ kí wọ́n lọ láti lọ wá ọ̀gá rẹ wá. Bóyá ẹ̀mí Olúwa ti gbé e sókè, ó sì gbé e kalẹ̀ lórí òkè ńlá tàbí lórí ilẹ̀.”“Rárá,” Èlíṣà dá a lóhùn pé, “Má ṣe rán wọn.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 2

Wo 2 Ọba 2:16 ni o tọ