Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíṣà rí èyí ó sì kígbe sókè, “Baba mi! Baba mi! Kẹ̀kẹ́ àti ẹlẹ́ṣin Ísírẹ́lì!” Èlíṣà kò sì rí i mọ́. Ó sì mú aṣọ ara rẹ̀ ó sì fà wọ́n ya sọ́tọ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 2

Wo 2 Ọba 2:12 ni o tọ