Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 18:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú ibi gíga náà kúrò, ó sì fọ́ òkúta àwọn ère ó sì gé àwọn ère lulẹ̀ ó sì fọ́ ejò idẹ náà túútúú tí Móṣè ti ṣe, títí di ọjọ́ tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń sun tùràrí sí. (Wọ́n sì pè é ní Néhúṣítanì.)

Ka pipe ipin 2 Ọba 18

Wo 2 Ọba 18:4 ni o tọ