Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 18:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báwo ni ìwọ yóò ṣe le padà sẹ́yìn ọ̀kan lára àwọn oníṣẹ́, tí ó gbẹ̀yìn lára àwọn oníṣẹ́ ọ̀gá mi, tí ó bá tilẹ̀ jẹ́ pé; ẹ̀yin gbẹ́kẹ̀ yín lé Éjíbítì fún àwọn kẹ̀kẹ́ àti ẹlẹ́ṣin?

Ka pipe ipin 2 Ọba 18

Wo 2 Ọba 18:24 ni o tọ