Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 18:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ìwọ bá sì sọ fún mi pé, “Àwa gbẹ́kẹ̀ wa lé Olúwa Ọlọ́run.” Òun ha kọ́ ní ẹnìkan náà tí ibi gíga àti àwọn pẹpẹ tí Heṣekáyà mú kúrò, tí ó wí fún Júdà àti Jérúsálẹ́mù pé, “O gbọdọ̀ sìn níwájú pẹpẹ yìí ní Jérúsálẹ́mù”?

Ka pipe ipin 2 Ọba 18

Wo 2 Ọba 18:22 ni o tọ