Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 18:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkókò yìí Heṣekáyà ọba Júdà ké wúrà tí ó wà ní ẹnu ìlẹ̀kùn ilé Olúwa, kúrò àti ti òpó tí Heṣekáyà ọba Júdà ti gbéró ó sì fi fún ọba Ásíríà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 18

Wo 2 Ọba 18:16 ni o tọ