Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 17:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní gbogbo ibi gíga, wọ́n ṣun tùràrí gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀èdè tí Olúwa ti lé jáde níwájú wọn. Wọ́n ṣe ohun búrubú tí ó rú ìbínú Olúwa sókè.

Ka pipe ipin 2 Ọba 17

Wo 2 Ọba 17:11 ni o tọ