Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 14:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà, Ámásáyà rán àwọn ìránṣẹ́ sí Jóásì ọmọ Jéhóáhásì ọmọ Jéhù ọba Ísírẹ́lì pẹ̀lú ìpèlẹ́jọ́ “Wá, í bá mi lójúkorojú.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 14

Wo 2 Ọba 14:8 ni o tọ