Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 14:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni ẹni tí ó ṣẹ́gun ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá ará Édómù ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ iyọ̀, ó sì fi agbára mú Ṣélà nínú ogun, tí ó ń pè é ní Jókítélì, orúkọ tí ó ní títí di òní.

Ka pipe ipin 2 Ọba 14

Wo 2 Ọba 14:7 ni o tọ