Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 14:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni ẹni tí ó ti dá àwọn ààlà Ísírẹ́lì padà láti Lebo-Hámátì sí òkú aginjù. Ní ìbámu pẹ̀lú ọ̀rọ̀ Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì, tí ó sọ nípasẹ̀ ìránṣẹ́ Jónà ọmọ Ámítaì, wòlíì láti Gátì Héférì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 14

Wo 2 Ọba 14:25 ni o tọ