Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 14:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéhóásì sì sinmi pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, a sì sin ín sí Ṣamáríà pẹ̀lú àwọn ọba Ísírẹ́lì. Jéróbóámù ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.

Ka pipe ipin 2 Ọba 14

Wo 2 Ọba 14:16 ni o tọ