Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 13:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kan ti ń sin òkú ọkùnrin kan, lójijì wọ́n rí ẹgbẹ́ àwọn oníjadì: Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ju òkú ọkùnrin náà sínú ibojì Èlíṣà. Nígbà tí ara ọkùnrin náà kan egungun Èlíṣà, ó padà wá sí ayé, ó sì dúró ní ẹsẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 13

Wo 2 Ọba 13:21 ni o tọ