Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 13:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ó wí pé, “Mú àwọn ọfà náà,” ọba sì mú wọn. Èlíṣà wí fún un pé, “Lu ilẹ̀.” Ó lù ú lẹ́ẹ̀mẹ́ta, ó sì dáwọ́ dúró.

Ka pipe ipin 2 Ọba 13

Wo 2 Ọba 13:18 ni o tọ