Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 13:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣí fèrèsé apá ìlà oòrùn,” ó wí, pẹ̀lú ó sì ṣéé: “Ta á!” Èlíṣà wí, ó sì ta á. “Ọfà ìṣẹ́gun Olúwa; ọfà ìṣẹ́gun lórí Ṣíríà!” Èlíṣà kéde. “Ìwọ yóò pa àwọn ará Ṣíríà run pátapáta ní Áfékì.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 13

Wo 2 Ọba 13:17 ni o tọ