Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 13:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ti ìyókù iṣẹ́ Jéhóásì fún ìgbà tí ó fi jọba, gbogbo ohun tí ó ṣe, pẹ̀lú àṣeyọrí rẹ̀ pẹ̀lú ogun rẹ̀ sí Ámásáyà ọba Júdà, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba Ísírẹ́lì?

Ka pipe ipin 2 Ọba 13

Wo 2 Ọba 13:12 ni o tọ