Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 13:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọdún kẹtàdínlógójì tí Jóásì ọba Júdà, Jéhóásì ọmọ Jéhóáhásì di ọba Ísírẹ́lì ní Ṣamáríà ó sì jọba fún ọdún mẹ́rìndínlógún.

Ka pipe ipin 2 Ọba 13

Wo 2 Ọba 13:10 ni o tọ