Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 12:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóásì ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Olúwa ní gbogbo ọdún tí Jéhóíádà àlùfáà fi àsẹ fún un.

Ka pipe ipin 2 Ọba 12

Wo 2 Ọba 12:2 ni o tọ