Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 12:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kò sì bá àwọn ọkùnrin náà sírò, ní ọwọ́ ẹni tí wọ́n fún ní owó láti san fún àwọn òṣìṣẹ́. Torí wọ́n ṣe é pẹ̀lú òdodo tí ó pé.

Ka pipe ipin 2 Ọba 12

Wo 2 Ọba 12:15 ni o tọ