Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 12:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Owó tí a mú wá sí ilé tí a kọ́ fún Olúwa kò jẹ́ níná fún ṣíṣe òpó fàdákà, àlùmágàjí fìtílà, àwokòtò, ipè, ohun èlò wúrà tàbí ohun èlò fàdákà kan fún ilé tí a kọ́ fún Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Ọba 12

Wo 2 Ọba 12:13 ni o tọ