Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 12:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìgbàkígbà tí wọ́n bá ti rí wí pé owó púpọ̀ wà nínú àpótí, akọ̀wé àti olórí àlùfáà yóò wá, wọ́n á ka owó náà tí wọ́n ti mú wá sí ilé tí a kọ́ fún Olúwa. Wọn a sì kó o sínú àwọn àpò.

Ka pipe ipin 2 Ọba 12

Wo 2 Ọba 12:10 ni o tọ