Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 10:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní kété tí Jéhù ti parí ṣíṣe ọrẹ sísun, ó pàṣẹ fún àwọn olùṣọ́ àti àwọn ìjòyè: “Wọlé lọ, kí o sì pa wọ́n; Má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni kí ó sálọ.” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n gé wọn lulẹ̀ pẹ̀lú idà. Àwọn olùṣọ́ àti ìjòyè ju ara wọn síta, wọ́n sì wọ inú ojúbọ ti ilé tí a kọ́ fún òrìṣà Báálì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 10

Wo 2 Ọba 10:25 ni o tọ