Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 10:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mú wọn láàyè!” ó pàṣẹ. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n mú wọn láàyè, wọ́n sì pa wọ́n ní ẹ̀bá kọ̀nga Bẹti-Ékédì, ọkùnrin méjìlélógójì. Kò sì fi ẹnìkan sílẹ̀ láìkù.

Ka pipe ipin 2 Ọba 10

Wo 2 Ọba 10:14 ni o tọ