Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 10:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó pàdé díẹ̀ lára àwọn ìbátan Áhásáyà ọba Júdà, ó sì béèrè, “Ta ni ẹ̀yin ń ṣe?”Wọ́n wí pé, “Àwa jẹ́ ìbátan Áhásáyà, àwa sì ti wá láti kí ìdílé ọba àti ti mọ̀mọ́ ayaba.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 10

Wo 2 Ọba 10:13 ni o tọ