Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 1:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ó sì kú, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa tí Èlíjà ti sọ.Nítorí Áhásáyà kò ní ọmọ, Jéhórámù jẹ ọba ní ọdún kejì tí Jéhórámù ọmọ Jèhósáfátì ọba Júdà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 1

Wo 2 Ọba 1:17 ni o tọ