Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 1:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọ fún ọba pé, “Èyí ni ohun tí Olúwa wí: Ṣé nítorí wí pé kò sí Ọlọ́run ní Ísírẹ́lì fún ọ láti pè ni ìwọ fi rán ìránṣẹ́ lọ sí ọ̀dọ̀ Bálísébúbù, òrìṣà Ékírónì láti lọ ṣe ìwádìí? Nítorí pé o ṣe èyí, ìwọ kò níi dìde lórí ibùsùn tí o dúbúlẹ̀ lé láìsí àní àní ìwọ yóò kú!”

Ka pipe ipin 2 Ọba 1

Wo 2 Ọba 1:16 ni o tọ