Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 1:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Tí Èmi bá jẹ́ ènìyàn Ọlọ́run,” Èlíjà sì dáhùn, “Ǹjẹ́ kí iná kí ó sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run kí ó sì jó ọ run àti àwọn àádọ́ta ènìyàn rẹ!” Nígbà náà iná Ọlọ́run sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run ó sì jó o run pẹ̀lú àwọn àádọ́ta ènìyàn rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 1

Wo 2 Ọba 1:12 ni o tọ