Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì tún rán balógun àádọ́ta pẹ̀lú àwọn ènìyàn àádọ́ta rẹ̀ sí Èlíjà. Balógun náà sì wí fún un pé, “Èniyàn Ọlọ́run, èyí ni ohun tí ọba ṣọ, ‘Ṣọ̀kalẹ̀ kánkán!’ ”

Ka pipe ipin 2 Ọba 1

Wo 2 Ọba 1:11 ni o tọ