Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 6:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Olúwa sọ fún Dáfídì baba mi pé, ‘Nítorí tí ó wà ní ọkàn rẹ láti kọ́ tẹ́ḿpìlì yìí fún orúkọ mi, ìwọ ṣe ohun dáradára láti ní èyí ní ọkàn rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:8 ni o tọ