Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 6:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Láti ọjọ́ tí èmi ti mú àwọn ènìyàn mi jáde kúrò ní ilẹ̀ Éjíbítì, èmi kò yan ìlú kan nínú gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì, láti kọ́ ilé, kí orúkọ mi kí ó lè wà níbẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni èmi kò yan ẹnikẹ́ni láti jẹ́ olórí lórí Ísirẹ́lì ènìyàn mi.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:5 ni o tọ