Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 6:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni ó sì wí pé:“Ògo ni fún Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, tí ó fi ọwọ́ rẹ̀ mú ohun tí ó fi ẹnu rẹ̀ sọ fún Dáfídì baba mi ṣẹ. Nitorí tí ó wí pé,

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:4 ni o tọ