Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 6:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nigbà náà, gbọ́ láti ọ̀run àni láti ibi ibùgbé rẹ, kí o sì ṣe ohun tí àwọn àlejò béèrè lọ́wọ́ rẹ. Bẹ́ẹ̀ ni kí gbogbo àwọn ènìyàn ayé kí wọn lè mọ orúkọ rẹ kí wọn sì bẹ̀rù rẹ, gẹ́gẹ́ bí Ísírẹ́lì ènìyàn rẹ ti se, kí wọn kí ó sì lè mọ̀ wí pé ilé yìí tí èmi ti kọ, orúkọ rẹ ni ó ń jẹ́.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:33 ni o tọ