Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 6:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní ti àwọn àlejò tí wọn kò sí lára àwọn ènìyàn rẹ Ísírẹ́lì ṣùgbọ́n tí wọ́n wá láti ọ̀nà jínjìn nítorí orúkọ ńlá rẹ àti ọwọ́ agbára rẹ àti nínà apá rẹ, nígbà tí ó bá wá tí ó sì gbàdúrà lórí ilé Olúwa yìí.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:32 ni o tọ