Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 6:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà tí ọkùnrin kan bá sì ṣe aburú sí aládùúgbò rẹ̀ tí ó sì gbà kí ó ṣe ìbúra tí ó sì wá tí o sì búra níwájú pẹpẹ rẹ nínú ilé Olúwa yìí,

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:22 ni o tọ