Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 6:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbọ́ ẹ̀bẹ̀ ìránṣẹ́ rẹ àti ti àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì nígbà tí wọ́n bá ń gbàdúrà lórí ibí yìí. Gbọ́ láti ọ̀run, ibùgbé rẹ, nígbà tí ìwọ bá sì gbọ́, dáríjìn.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:21 ni o tọ